HYMNS FOR TIME OF TRIAL | C&S Church Online
Logo

C&S Church Online

HYMNS FOR TIME OF TRIAL

Article Image

 

Below are hymns to sing when facing trouble, tribulation or trials in your Life, Ministry or Marriage. 

 

THIRD EDITION ( HYMN 559)

 

1.

KRISTIAN , MA TI WA SINMI

GBO B'ANGELI RE TI N WI

NI ARIN OTA L'O WA,

MA SORA.

 

2.

OGUN ORUN -APADI,

T'A KO RI N KO RA WON JO

WON N SO IJAFARA RE

MA SORA 

 

3.

AWON T'O SEGUN SAJU

WON WO WA B'AWA TI N JA

WON N FI OHUN KAN WIPE

MA SORA 

 

4.

MA SORA BI ENI PE

NIBE NI SEGUN RE WA 

GBADURA FUN RANWO

MA SORA

 

...................

THIRD EDITION ( HYMN 257)

 

1.

JESU, NIGBA 'DANWO,

GBADURA FUN MI,

K' EMI MA BA SE O

KI N SI SAKO LO,

GBA MBA SIYEMEJI,

K'O BOJUWOMI;

K'ERU TAB' ISOJI

MA MU MI SUBU

 

2.

B'AYE BA SI N FA MI,

PELU ADUN RE;

T'OHUN SURA AYE

FE HAN MI L'EMO;

JO MU GETSEMANE

WA S'ITANTI MI,

TABI IRORA RE,

LOKE KALFARI.

 

3.

B'O BA PON MI LOJU,

NINU IFE RE ;

DA IBUKUN RE LE 

ORI EBO NA :

KI N F'ARA MI FUN O

LORI PEPE RE 

B'ARA KO AGO NA

IGBAGBO Y'OMU.

 

........................

 

THIRD EDITION (556)

 

1.

MA TOJU MI JEHOFA NLA

ERO L'AYE OSI YI,

EMI KO N' OKUN, IWO NI

F' OW'AGBARA DI MI MU

OUNJE ORUN, ONJE ORUN,

MA BO MI TITI LAILAI

 

2.

GBA MO BA TE EBA JORDAN

F'OKAN ERU MI BALE

IWO T'O TI SEGUN IKU

MU MI GUNLE KENAAN JE;

ORIN IYIN, ORIN IYIN 

L' EMI O FUN O TITI .

 

AMIN.

..........................

 

PRAY WITH THESE HYMNS 

 

Posted on 5/8/2026, 1:50:42 PM
0 0